E ba mi Kalleluya Reloaded Lyrics
Eh Gbogbo eniyan ni gbogbo agabaye
Lor′igun mererin aaye
Ni gusu ni ariwa ni iwo oorun ni ila orun
E wa kajo yin Jesu Kristi
Oba taa bi lo ni
Aha ehehe E gbo
E ba mi k'alleluyah s′Olorun wa
E ba mi k'alleluyah s'Olorun wa
Igbala de o fun wa l′omo re Jesu Kristi
E ba mi k′alleluyah s'Olorun wa
O fun wa layo o, ehn
Iye to ye koro, ehn
Igbega n be, ehn
Alaafia to tayo, ehn
Idalare otun, ehn
Iye ainipekun, ehn
Ijoba ayeraye
Iroyin ayo ni Jesu yi mu wa fun wa
We thank you Jesus for coming here
And to be borne by virgin Mary
And your story is story is so glorious
And you have come to change our story
E ba mi k′alleluyah s'Olorun wa
E ba mi k′alleluyah s'Olorun wa
Igbala de o fun wa l′omo re Jesu Kristi
E ba mi k'alleluyah s'Olorun wa
Gbongbo idile Jese ta n pe Jesu
Oba to wa s′aye pelu irele
Itana sharoni ti ko le ku
Odo aguntan, Olugbala wa ni
E ba mi k′alleluyah s'Olorun wa
E ba mi k′alleluyah s'Olorun wa
Igbala de o fun wa l′omo re Jesu Kristi
E ba mi k'alleluyah s′Olorun wa
E ba mi k'alleluyah s'Olorun wa
E ba mi k′alleluyah s′Olorun wa
Igbala de o fun wa l'omo re Jesu Kristi
E ba mi k′alleluyah s'Olorun wa